Tope Alabi, a Nigerian gospel music veteran, has released the visual for her powerful worship song "Sami Iyin," which is part of her highly impressive album “Oluwa Ni”.
The visual for "Sami Iyin" complements the powerful worship song, adding an even more impressive visual element to the music
"Sami Iyin" is a song that expresses gratitude and joy in a simple yet powerful manner, featuring a mix of old and new sounds
Fans have expressed their admiration for the song and its video, with comments praising Tope Alabi's inspirational teaching through her music.
Watch Video & Download Audio Below;
Stream & Download Audio Below;
Lyrics: Sami Iyin By Tope Alabi
Sami iyin simi l’ara kin tesiwaju
Sami iyin simi l’ara kin ma le duro
Sami iyin simi l’ara kin tesiwaju
Sami iyin simi l’ara kin ma le duro
Ki yin o o l’ati owuro d’ale
Ko ma ma to mi kin tun wo nu si ajin
Sami iyin simi kin ma le duro
Mo mo pe ti ba ti sami iyin
Ti n ba gba ami iyin
Mo ti gb’ami iye
Ti n ba gba ami iyin
Mo ti gb’ami ogo
Ti n ba gba ami iyin
Mo ti gb’ami iye
Mo gb’ami owo
Mo gb’ami ola
Mo gb’ami alafia
Aiku baale oro
Sami iye simi…
Sami iyin simi
Sami iyin simi
Sami iyin simi
Kin ma le duro
Sami iyin simi
Sami iyin simi
Sami iyin simi
Kin ma le duro